2023 WORSHIP ON WAVES IJOSIN

FEBRUARY, 2023

WoW 296 – Apá Ìkẹfa- Mo fẹ́ràn láti má ká orin Dáfídì nítorí wípé Olúwa rántí èmi na ninu rẹ; Ps. 23: 1-6 and John 10: 10-15. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 295 – Apá Ìkarun – Mo fẹ́ràn láti má ká orin Dáfídì nítorí wípé Olúwa rántí èmi na ninu rẹ; Ps. 23: 1-3 and John 10: 10-15. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

JANUARY, 2023

WoW 294 – Apá Ìkerin – Mo fẹ́ràn láti má ká orin Dáfídì nítorí wípé Olúwa rántí èmi na ninu rẹ; Ps. 23: 1-3 and John 10: 10-15. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 293 – Apá Ìkẹta – Mo fẹ́ràn láti má ká orin Dáfídì nítorí wípé Olúwa rántí èmi na ninu rẹ; Ps. 23: 1-3 and Luke 24: 44 Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 292 – Apá Ìkejì – Mo fẹ́ràn láti má ká orin Dáfídì nítorí wípé Olúwa rántí èmi na ninu rẹ; Orin Dafidi 23: 1-3 and Luku 24: 44 – Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 291 – Mo fẹ́ràn láti má ká orin Dáfídì nítorí wípé Olúwa rántí èmi na ninu rẹ; Orin Dafidi 23: 1-3 and Luku 24: 44 – Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 287 – Fun ànfàní ara mi, èmi yio jíròrò pẹlu Edumare ni 2023, Sẹfanáyà 3: 1-7 – Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

2022 WORSHIP ON WAVES IJOSIN

DECEMBER, 2022

WoW 286 – Ní 2022 mo rí ìtọ́ni Ọlọ́run – Olusola Makindipe. Orin Dáfídì 23:1-3
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 285 – Ǹjẹ́ lakoko yí, ṣe Kérésìmesì sì ṣe pàtàkì sì mi? Mika 5: 2-7 & Jòhánù 3:16.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 278 – Adventi Apá ìkẹrin lórí ‘Adventi 2022 ni mí niran imoore àti ìfẹ́ ńlá Olódùmarè’- Neh. 4: 14-21 & 1 Thess. 5: 16-18. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 271 – Adventi Apá ìketa lórí ‘Adventi ni mí niran pípa ọna mọ fún bi bọ Kristi’- Jẹ́nẹ́sísì 5: 21-24 & Lúùkù 1: 5-20. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 264 – Adventi Apá ìkejì lórí ‘Ohun tí Jésù fẹ́ láti ọwọ mi’- Aísáyà 6: 1-8 & Jòhánù 17: 21-25. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

NOVEMBER, 2022

WoW 257 – Apá Ikinni lórí ‘Jésù lọ Ọba Adventi’- Aísáyà 9: 6-7 & Mátíù 1: 1, 18-23. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 256 – Apá Ógbon lórí ‘Agbára dídá ayé – Jẹ́nẹ́sísì 8: 1-end & OD 51:7-11. Olusola Makindipe.
 
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 255 – Apá Ọkàn-din-l’Ógbon lórí ‘Agbára dídá ayé – Jẹ́nẹ́sísì 7: 1-end & Jòhánù 3:1-3. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 254 – Apá Meji-din-l’Ógbon lórí ‘Agbára dídá ayé – Jẹ́nẹ́sísì 6: 14-21. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

OCTOBER, 2022

WoW 253 – Apá Meta-din-l’Ógbon lórí ‘Agbára dídá ayé – Jẹ́nẹ́sísì 6: 13-22 &  Orin Dáfídì 24: 3-5. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 252 – Apá Merin-din-l’Ógbon lórí ‘Agbára dídá ayé – Jẹ́nẹ́sísì 6: 1-13 & Pétérù kejì 2: 5. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 251 – Apá Marun-din-l’Ógbon lórí ‘Agbára dídá ayé – Jẹ́nẹ́sísì 5: 3-32 & Lúùkù 3: 36-38. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 250 – Apá Mẹrin-le-l’Ógun lórí ‘Agbára dídá ayé – Jẹ́nẹ́sísì 4: 23-24 & Kọ́ríńtì kejì 10: 4. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 249 – Apá Mẹta-le-l’Ógun lórí ‘Agbára dídá ayé – Jẹ́nẹ́sísì 5: 1-2 & Aísáyà 65: 17. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

SEPTEMBER, 2022

WoW 248 – Apá Meji-le-l’Ógun lórí ‘Agbára dídá ayé – Jẹ́nẹ́sísì 4: 23-24 & Jòhánù 18: 1-11. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 247 – Apá ọkàn-le-l’Ógun lórí ‘Agbára dídá ayé – Jẹ́nẹ́sísì 4: 23-24 & Jòhánù 18: 1-11. Olusola Makindipe
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 246 – Apá Ógun lórí ‘Agbára dídá ayé. Jẹ́nẹ́sísì 4: 17-26. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 245 – Apá Ìkankandinlogun lórí ‘Agbára dídá ayé. Jẹ́nẹ́sísì 4: 3-16 & Kólósè 1: 27. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 244 – Apá Ìkejidinlogun lórí ‘Agbára dídá ayé. Jẹ́nẹ́sísì 4: 1-2. Olusola Makindipe.

DOWNLOAD SERVICE

AUGUST, 2022

WoW 243 – Apá Ìketadinlogun lórí ‘Agbára dídá ayé. Jẹ́nẹ́sísì 3: 22-24. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 242 – Apá Ìkerindinlogun lórí ‘Agbára dídá ayé. Jẹ́nẹ́sísì 3: 22-24. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 241 – Apá Ìkarundinlogun lórí ‘Agbára dídá ayé. Jẹ́nẹ́sísì 3: 15, 22-24 & Luku 1: 26-30. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 240 – Apá Ìkẹrinla lórí ‘Agbára dídá ayé. Jẹ́nẹ́sísì 3: 14-22 & Heb. 9: 27. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

JULY, 2022

WoW 239 – Apá Ìketalá lórí ‘Agbára dídá ayé. Jẹ́nẹ́sísì 3: 7-13. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 238 – Apá Ìkejilá lórí ‘Agbára dídá ayé. Jẹ́nẹ́sísì 3: 7-13. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 237 – Apá Ìkankanlá. lórí ‘Agbára dídá ayé. Jẹ́nẹ́sísì 3: 1-7. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 236 – Apá Ikẹwá. lórí ‘Agbára dídá ayé. Jẹ́nẹ́sísì 2: 21-25 & Jòhánù 2: 1-12. Olusola Makindipe..
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 235 – Apá Ikẹsàn-án lórí ‘Agbára dídá ayé. Jẹ́nẹ́sísì 2: 21-25. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

JUNE, 2022

WoW 234 – Apá ikejo lórí ‘Agbára dídá ayé. Jẹ́nẹ́sísì 2: 16-20. Olusola Makindipe.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 233 – Ọjọ́ ìsinmi ajoyo àwọn bàbà, ní Apá Ìkeje – ‘Agbára dídá ayé. Jẹ́nẹ́sísì 2: 4b-15 àti Jòhánù 10: 29-30. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 232 – Ọjọ́ ìsinmi Mẹ́talọ́kan àti ọjọ́ ìjọba tíwan tíwan – ‘Agbára dídá ayé – Apá Ìkẹfa. Jẹ́nẹ́sísì 2: 1-4a àti Jòhánù 14: 25-26. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 231 – ‘Agbára dídá ayé- Apá Ìkarún. Jẹ́nẹ́sísì 1:24-31 àti Ìṣe àwọn Apọ́sítélì 2:1-13. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.
 

DOWNLOAD SERVICE

MAY, 2022

WoW 230 – ‘Agbára dídá ayé- Apá Ìkẹrin. Jẹ́nẹ́sísì 1:20-23. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

WoW 229 – ‘Ọjọ́ ìgòkè rè ọrùn Kristi – Ìṣe àwọn Apọ́sítélì 1: 6-11. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 228 – ‘Ọjọ́ àwọn Wesley – Romu 1: 17. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

WoW 227 – ‘Agbára dídá ayé- Apá Ìkẹta. Jẹ́nẹ́sísì 1:14-19. Olúṣọlà Mákindipẹ̀
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 226 – ‘Agbára dídá ayé- Apá Ìkeji. Jẹ́nẹ́sísì 1:9-13 and Lúùkù 22:36. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 225 – ‘Agbára dídá ayé- Apá Ìkíni – Jẹ́nẹ́sísì 1 :1-8. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 224 – ‘Òtítọ́ ni agbára Ajinde kúrò nínú òkú jẹ – Apá Ìkẹta – 1 Kọ́ríńtì 15:12-34. Olúṣọlà Mákindipẹ̀
 

DOWNLOAD SERVICE

APRIL, 2022

WoW 223 – ‘Òtítọ́ ni agbára Ajinde kúrò nínú òkú jẹ – Apá Ikeji – 1 Kọ́ríńtì 15. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 222 – ‘Òtítọ́ ni agbára Ajinde kúrò nínú òkú jẹ – 1 Kọ́ríńtì 15: 35-58 & Matt 28: 1-10. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

WoW 215 – ‘Fe ẹnikẹ́ji rẹ bí ara rẹ’ – ‘njẹ ó sèsé ni Naijiria bi? – Sef. 3: 15-17 & Luku 10: 25-37. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

WoW 207 – ‘Ọlọrun ayérayé ni ààbò mi’ – Diut. 33: 27 & Mátíù 11: 12. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

MARCH, 2022

WoW 199 – Apá Ikeji – ‘Ọjọ́ ìdùnnú’ – Rutu 4: 1-13. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

WoW 191 – Apá Ikìnnì – ‘Ọjọ́ ìdùnnú tí àgbáyé’ – Òwe 18: 22 & Pétérù kini 1: 5-6. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 183 – Apá Ikeji – ‘Kí lóde tí mo ṣe gbà awẹ? ‘ – Aísáyà 58: 6-9a. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 175 – ‘Kí lóde tí mo ṣe gbà awẹ? ‘ – Aísáyà 58: 6-9a. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.
 

DOWNLOAD SERVICE

FEBRUARY, 2022

WoW 169 – Apá Ìkẹrin: ‘Fi ọpẹ fún akọrọ ojo’ – Jòhánù 4: 26-42. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

WoW 168 – Apá Ìkẹta: ‘Fi ọpẹ fún akọrọ ojo’ – Jòhánù 4: 25-26. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 167 – Apá Ikeji: ‘Fi ọpẹ fún akọrọ ojo’ – Orin Dafidi 46: 10 and Jòhánù 4: 15: – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.
 

DOWNLOAD SERVICE

WoW 166 – Apá Ikìnnì: ‘Fi ọpẹ fún akọrọ ojo’ – OD 46: 10 and Jòhánù 4: 15: – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.
 

DOWNLOAD SERVICE

JANUARY, 2022

WoW 165 – Apá kejì ‘Bawo ni ọrọ Ọlọ́run, ṣé lé di imunadoko láti ọwọ mi?’ – Jóṣúà 1: 1-9 and Àwọn Ọba kejì 4: 8ffl: – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

WoW 164 – ‘Bawo ni ọrọ Ọlọ́run, ṣé lé di imunadoko láti ọwọ mi?’ – Jóṣúà 1: 1-9 and Lúùkù 1: 1-4; 4: 14-21: – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

WoW 163 – ‘Gẹ́gẹ́bí imọle Ọlọ́run, Jésù pàrọwà sí mi láti fí ará mi yẹ Ọlọ́run sí’ – Aísáyà 60: 1-6 àti 1
Kọ́ríńtì 6: 12-20 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

WoW 162 – ‘Anfàní àdúrà fun ọjọ́ mẹwa’ – Lúùkù 1: 30 & 37 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

WoW 161 – ‘Anfàní gbígbà àdúrà kí Krístì lé jẹ́ imole aiyé ẹnì’ – Aísáyà 60: 1-6 àti Lúùkù 1:30, 35-37 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

WoW 160 lórí ‘Anfàní àdúrà fun ọjọ́ mẹwa’ – Lúùkù 1: 30 & 37 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

Kérésìmesì ìlà-oòrùn – WoW 159 lórí ‘Anfàní àdúrà fun ọjọ́ mẹwa’ – Lúùkù 1: 30 & 37 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

Epifani – WoW 158 lórí ‘Anfàní àdúrà fun ọjọ́ mẹwa’ – Lúùkù 1: 30 & 37 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

WoW 157 lórí ‘Anfàní àdúrà fun ọjọ́ mẹwa’ – Lúùkù 1: 30 & 37 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

WoW 156 lórí ‘Anfàní àdúrà fun ọjọ́ mẹwa’ – Lúùkù 1v37 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

Wow 154 nínú ìjọsìn Májẹ̀mú dídá, lórí: ‘Fún ànfàní àrà mi, ẹ jẹ ká jíròrò pẹlu Èdùmàrè nínú àdúrà’ – Lúùkù 1v37: Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

2021 WORSHIP ON WAVES IJOSIN

DECEMBER, 2021

WOW 153- Orin Dafidi 9:1-2 ati 150, lori; Aroju Ire Oluwa ni 2021  – Olusola Makindipe

DOWNLOAD SERVICE

WOW 152- Lúùkù 2:35b; Mátíù 2:18; and Hébérù 2:10, lórí: Ọjọ́ Ẹtì Rere bẹ̀rẹ̀ ní àkókò ìbí Krístì – Temitayo Okunoren.

DOWNLOAD SERVICE

WOW 152- Lúùkù 2:35b; Mátíù 2:18; and Hébérù 2:10, lórí: Ọjọ́ Ẹtì Rere bẹ̀rẹ̀ ní àkókò ìbí Krístì – Temitayo Okunoren.

DOWNLOAD SERVICE

WOW 151- Kérésìmesì lórí Jòhánù 3: 16: ‘Ni Kérésìmesì 2021 Jésù Kristi fẹ́ kin fi ifẹ han, kìí ṣe ikórìíra’ – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

WOW 150- Adfenti kerin: Orin Dáfídì 23: ‘Ni Adfenti Jésù Kristi ni Olusoaguntan kan ṣoṣo tí mo ni’ – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

WOW 149 – Adfenti Keta: Jòhánù 1: 1-14: ‘Ni Adfenti ìfẹ́ Jésù ló wò àrùn irobinuje ọkàn mi san’ – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

WOW 148th – Adfenti keji: Luku 1: 39-45 : ‘Adfenti mu Àlàáfíà ńlá julọ ba mi’ – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

NOVEMBER, 2021

WOW 147th -Adfenti kini: Isaiah 9:6-7 : ‘Adfenti mu ìrètí ńlá jù lọ ba mi’ – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

WOW 146th -Apá Ìkesan lórí Ìwé Òwe 14v34: ‘Báwo ni Ọlọ́run wà ṣé tóbi tó, nínú ètò ìṣe ilu? ati Apa Ìkejilà: Ìjẹ Jésù jíǹde kúrò nínú òkú? Ṣé ìtàn tàbí òtítọ́ ni?’ – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

WOW 145th – Apá Ìkejo lórí Luku 13: 1-5 : ‘Báwo ni Ọlọ́run wà ṣé tóbi tó, nínú ètò ìṣe ilu?’ – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

WOW 144th – Apa Ikeje ti lori Iwe Owe 14:34 ati Heberu 2: 3:  ‘Bawo ni Olorun wa se tobi to, ninu eto ise ilu? – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

OCTOBER, 2021

WOW 143 – Apá Ìkefa lórí Iwo Owe 14:34 : ‘Báwo ni Ọlọ́run wà ṣé tóbi tó, nínú ètò ìṣe ilu?’ – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD  SERVICE

WOW 142 – Apá Ìkarun lórí Luku 13: 1-5 : ‘Báwo ni Ọlọ́run wà ṣé tóbi tó, nínú ètò ìṣe ilu?’ – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD  SERVICE

WOW 141st – Apá Ìkẹrin lórí Jer. 31: 15 : ‘Báwo ni Ọlọ́run wà ṣé tóbi tó, nínú ètò ìṣe ilu?’ – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD  SERVICE

WOW 140th – Apá Ìketa lori Orin Dafidi: ‘Báwo ni Ọlọ́run wà ṣé tóbi tó, nínú ètò ìṣe ilu?’ – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

WOW 139th – Apá Ìkeji: ‘Báwo ni Ọlọ́run wà ṣé tóbi tó, nínú ètò ìṣe ilu?’ – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

WOW 138th – Apa ikini ti 2 Kironika 7:14 ati Matiu 5:11 lori wipe, ‘Bawo ni Olorun wa se tobi to, ninu eto ise ilu? – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

SEPTEMBER, 2021

WoW 137th-Apa Ikejila lori Orin Dafidi 118 lori wipe Ri wipe Igbala Kristi je tire o -Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

WOW 136th Ajoyo odun mokan-din-ni-ogosan ti Ijo Kristi ni Naijiria!- Olúṣọlà Mákindipẹ

DOWNLOAD SERVICE

WOW 135th – Apá Ikankola ti Orin Dafidi 118 lori wípé, Afe se igbeyawo bi? Ma sona ko si ma gba adura- Olúṣọlà Mákindipẹ

DOWNLOAD SERVICE

WOW 134th – Apá Ikewa ti Orin Dafidi 118 lori wípé, Ìtura ọkàn náà ha dà?- Olúṣọlà Mákindipẹ

DOWNLOAD SERVICE

WOW 133rd – Apá Ikesan ti Orin Dafidi 118 lori wípé, Iyonda lati se igboran- Olúṣọlà Mákindipẹ

DOWNLOAD SERVICE

AUGUST, 2021

WOW 132nd – Apá Ikẹjo  ti Orin Dafidi 118 lori wípé, Si so okan mi pelu alaapon’ – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

WOW 131st – Apá Ikẹje  ti Orin Dafidi 118 lori wípé, ‘Ikẹ́kọ̀ọ́ ọna òdòdó Ọlọ́run’ – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

WOW 130th – Apá Ikẹfà ti Orin Dafidi 118 lori wípé, ‘Ń rìn ni ọna toro na’ – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

WOW 129th – Apá ikarun ti Orin Dafidi 118 lori wípé, ‘Mo ni láti kò ipá tèmi kín le wà láàyè – Olúṣọlà Mákindipẹ  

DOWNLOAD SERVICE

WOW 128th – Apá ikerin ti Orin Dafidi 118 lori wípé, Ìgbàlà jẹ èso ìgbọràn- Olúṣọlà Mákindipẹ

DOWNLOAD SERVICE

JULY, 2021

WoW 127th – Apá keta ti Orin Dafidi 118 lori wípé, Ìgbàlà wa nípasẹ̀ òkúta ọmọlé – Olusola Makindipe.

DOWNLOAD SERVICE

WoW 126th – Apá keji ti Orin Dafidi 118: 22-26 lori wípé, Kristi ni òkúta ọmọlé – Olusola Makindipe.

DOWNLOAD SERVICE

WoW 125th –
Fífì imore fún Olúwa – Apá kini ti Orin Dafidi 118: 1-9 – Olusola Makindipe.

DOWNLOAD SERVICE

WoW 124th –
Oluwa ni Alabo mi – Orin Dafidi 20: 5-9 – Olusola Makindipe.

DOWNLOAD SERVICE

JUNE, 2021

WoW 123rd,
Àdúrà fún Ààbò – Orin Dafidi 20: 1-5 – Olusola Makindipe.

DOWNLOAD SERVICE

WoW 122 – Tani Okọ Obìnrin Oníwà Rere? Iwe Owe 31:23,  Ẹni Ọ̀wọ̀ Temitayo Okunoren-Makindipe.

DOWNLOAD SERVICE

WoW 121 – Àdúrà-orin aró fún Ìjọ Kristi àti Naijiria: Orin Dáfídì 88 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

WoW 120 – Apá Ikẹwa – Njẹ Jesu jíǹde nitõtọ kúrò nínú òkú? Léfítíkù 8: 31-36 ati Jòhánù 20: 24-31 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

MAY , 2021

WoW 119 – Apá Ikẹsan – Njẹ Jesu jínde nitõtọ kúrò nínú òkú? Hábákúkù 2: 4 ati Jòhánù 20: 24-28 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

WoW 117 – Apá Ikeje – Ìjẹ Jesu jíǹde nitõtọ kúrò nínú òkú? Ìṣe Àwọn Àpọ́sítélì 2: 4 ati Jòhánù 20: 24-31 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

WoW 116 – Apá Ikẹfà – Njẹ Jesu jíǹde nitõtọ kúrò nínú òkú? Jòhánù 20: 24-31 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

WoW 114- Apa Ikarun – Ije Jesu jinde nitoto kuro ninu oku? Ise Awon Apositeli 8:26-40 ati Johanu 20: 24-31 – Olusola Makindipe

DOWNLOAD SERVICE

WoW 113- Apa Ikarin – Nje Jesu jinde nitoto kuro ninu oku?  Johanu 20: 24-31 – Olusola Makindipe

DOWNLOAD SERVICE

APRIL, 2021

WoW 112- Apa Iketa – Nje Jesu jinde nitoto kuro ninu oku?  Johanu 20: 24-31 – Olusola Makindipe

DOWNLOAD SERVICE

WoW 111- Apa Keji – Ije Jesu jinde nitoto kuro ninu oku? Johanu 20:19-31 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

WoW 110 – Nje Jesu jinde nitoto kuro ninu oku? Johanu 20:19-31 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

WoW 109 – Òwúrọ Àjíǹde, April 4, 2021. ‘Talo pa, Jesu: Ṣe Jù, Romu, Pílátù, Onigbagbọ tàbí Ọlọ́run?’ Mátíù 27: 25 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

MARCH, 2021

WoW 102 – March 28, 2021. L’ojo isin imo ọpẹ, Kini orin isegun mi? – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

WoW 94 Yoruba: Àkọ́lé Ìwàásù: Oore-Ofe Apa 5 – Oore Ofe Jesu Kristi Oluwa wa – Sinmi  ninu re- Tèmítáyọ̀ Okùnọ́ọ̀rẹ̀n

DOWNLOAD SERVICE

WoW 86 Yoruba: Àkọ́lé Ìwàásù: Oore-Ofe Apa 4 – Oore Ofe Jesus Kristi Oluwa wa – Ifihan ninu obinrin – Tèmítáyọ̀ Okùnọ́ọ̀rẹ̀n

DOWNLOAD SERVICE

WoW 78 Yoruba: Àkọ́lé Ìwàásù: Oore-Ofe Apa 3 – Oore Ofe Jesus Kristi Oluwa wa – nje o gba a gbo bi? – Tèmítáyọ̀ Okùnọ́ọ̀rẹ̀n

DOWNLOAD SERVICE

FEBRUARY, 2021

WoW 70 Yoruba: Àkọ́lé Ìwàásù: Oore-Ofe Apa 2 – Oore Ofe Jesus Kristi Oluwa wa – nje o ti tewogba a? – Tèmítáyọ̀ Okùnọ́ọ̀rẹ̀n

DOWNLOAD SERVICE

WoW 62 Yoruba: Àkọ́lé Ìwàásù: Òmìnira jẹ ìfarahàn ore-ofẹ. Exodus 21: 1-11 & 2 Corinth. 13: 14 – Tèmítáyọ̀ Okùnọ́ọ̀rẹ̀n

DOWNLOAD SERVICE

WoW 56 Yoruba: Àkọ́lé Ìwàásù: Ìpaláradá: Ṣe o pọndandan fun mi ni? Máàkù 9: 2, 4 & 7b – Tèmítáyọ̀ Okùnọ́ọ̀rẹ̀n

DOWNLOAD SERVICE

WoW 55 Yoruba ti Òjó Ìsinmi Ìkarun lẹhin Epifani: Àkọ́lé Ìwàásù: “Ni 2021, bí pápá o ba fúnra, pápá a jó”. Kókó Ìwàásù: Àwọn Oba kini 19: 4-8 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERVICE

JANUARY, 2021

WoW 54 Yoruba ti Òjó Ìsinmi Ikerin lẹhin Epifani: Àkọ́lé Ìwàásù: Apá Ìkerin – Ìfihàn Kristi je ibere irin ajo ominira mi”  Kókó Ìwàásù: Efesu 4:20 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

 

WoW 53 Yoruba ti Òjó Ìsinmi Ìkẹta lẹhin Epifani: Àkọ́lé Ìwàásù: Apá Ìkẹta – Ìfihàn Kristi fun Aísáyà mú òmìnira nínú ẹ̀mí bá”. Kókó Ìwàásù: Aísáyà 1:19 & 6: 8 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERVICE

WoW 52 Yoruba ti Òjó Ìsinmi keji lẹhin Epifani: Àkọ́lé Ìwàásù: Apa Ikeji  -Ifihan Kristi fun awa keferi dabi eto Ominira Oselu “. Kókó Ìwàásù: Aisaya 57:17-21 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERMON

WoW 51 Yoruba ti Òjó Ìsinmi kini lẹhin Epifani: Àkọ́lé Ìwàásù: Apa Ìkíni “Kini ìtumọ̀ Epifani/ Ifarahàn Kristi? “. Kókó Ìwàásù: Mátíù 2:1 – 12 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD SERMON

WoW 50 Yoruba Ìsìn Májẹ̀mú: Àkọ́lé Ìwàásù: “Ma ṣe bẹ̀rù”. Kókó Ìwàásù: Aísáyà: 43: 1 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD SERMON

2020 WORSHIP ON WAVES IJOSIN

DECEMBER, 2020

WOW 49 – Yoruba Watchnight Service by Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

 

WoW 48 Yoruba: Àkọ́lé Ìwàásù: Apa Ìkeji “Ìgbàgbọ́ pẹ̀lú Imoore – .’ Kókó Ìwàásù: 1 Thess: 4 18 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

 Eto ìjọsìn fun ọjọ́ ìbí Jesu ti a npe ni Kérésìmesì. WoW 47 Yoruba: Àkọ́lé Ìwàásù: “Ki’ko orin Jésù ní àkókò yi.’ Kókó Ìwàásù: Matt. 1:18-21 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

Àkọ́lé Ìwàásù: WoW 46 Yoruba: Àkọ́lé Ìwàásù: Adfenti apa Ìkẹrin ati Apa Ìkíni “Ìgbàgbọ́ pẹ̀lú Imoore – .’ Kókó Ìwàásù: 1 Thess: 4 18 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

Àkọ́lé Ìwàásù: WoW 45 Yoruba: Àkọ́lé Ìwàásù: “Pípa lẹ ọkàn mí mọ – Adfenti apa Ìkẹta.’ Kókó Ìwàásù: Luku 1: 16-17 – Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

Àkọ́lé Ìwàásù: WoW 44 Yoruba: Àkọ́lé Ìwàásù: “Ǹjẹ́ kíni Jésù ń fẹ́ lọdọ mí ni àkọ́kọ́ yi? – Adfenti apa Ìkeji.’ Kókó Ìwàásù: Jòhánù 17:24 – Olúṣọlà Mákindipẹ.

DOWNLOAD

NOVEMBER, 2020

Àkọ́lé Ìwàásù:  “Ǹjẹ́ Jésù ni Olúwa Adfenti bí? – Apa Ìkíni.’ Kókó Ìwàásù: Isaiah 9: 6-7 by Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

 

Àkọ́lé Ìwàásù:  “Naijiria@60: Iwa ìsìnwín Ọba Saulu ló mú ìparun dé ba. Apa Kẹ̀sán.’ Kókó Ìwàásù: Sámúẹ́lì kini 9: 1-2 & 13:11-14 by Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

Àkọ́lé Ìwàásù:  “Naijiria@60: Gídíónì ati ẹrù ọkàn rẹ fún Nàìjíríà. Apa Kẹjọ.’ Kókó Ìwàásù: Àwọn Onidajọ 6: 1, 6, 25-32. by Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

Àkọ́lé Ìwàásù: WoW 40 Yoruba: Àkọ́lé Ìwàásù: “Naijiria@60: Gídíónì ati ẹrù ọkàn rẹ fún Nàìjíríà. Apa Keje.’ Kókó Ìwàásù: Àwọn Onidajọ 6: 1, 6, 25-32. by Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

 

Àkọ́lé Ìwàásù: WoW 39 Yoruba: Àkọ́lé Ìwàásù: “Naijiria@60: Wòlíì Isaiah ati erongba rẹ fún Naijiria. Apa Kẹfa.’ Kókó Ìwàásù: Isaiah 6:b, Mátíù 5: 48. by Olusola Makindipe

DOWNLOAD

 

OCTOBER, 2020

Àkọ́lé Ìwàásù: “Naijiria@60: Àwọn ojẹ wẹ́wẹ́ akíkanjú wà, n kú lọ. Apa Kẹrin.’ Kókó Ìwàásù: Mátíù 2: 13-18. Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

Àkọ́lé Ìwàásù: Naijiria@60: Iwa fífi ìhónú wa han, jẹ eto ìpèsè Ẹlẹ́dàá láti ọwọ adẹtẹ merin ti Samáríà. Apa Keta.’ Kókó Ìwàásù: 2 Kings 7: 1-10, Phil. 2: 1-6. Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD

Àkọ́lé Ìwàásù: Naijiria @60: Jòhánù Onitẹbọmi ati ẹka aabo ilu Naijiria. Apa Keji.’ Kókó Ìwàásù: Luku 3: 13-14 by Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD

Àkọ́lé Ìwàásù: Naijiria @ 60: Iru orugbe wo, lon gbe wa? Apa Kini. ‘Koko Iwaasu: Ekisodu 17:1-7 & Johanu 4: 14 by Olusola Makindipe

DOWNLOAD

 

SEPTEMBER, 2020

Àkọ́lé Ìwàásù: “Oluwa, ìbá jẹ́ pé o wà níhìn-ín, arakunrin mi kì bá tí kú!’  Kókó Ìwàásù: Jòhánù 11: 21-23. Olúṣọlà Mákindipẹ̀

DOWNLOAD

Àkọ́lé Ìwàásù: Ayajo ojo ibi Ikeji din l’ogosan-an Esin Onigbagbo ati Ijo Eleto ni ilu Naijiria

DOWNLOAD

 

Àkọ́lé Ìwàásù: ‘Fífì imore hàn sí Olúwa ninu orin kíkọ fún ìpèsè’ Kókó Ìwàásù: Orin Dáfídì 150 By Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

Àkọ́lé Ìwàásù: ‘Ògbólógbòó Baba Àgbà ti Àgbáyé’ (Apá Iketala) tàbí ‘’Apá ikokandinlogun: – ‘Ní bo ní àgbárá ìwòsàn Ọlọ́run wà lákòókò àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà tó gbayé kan, báyìí? Kókó Ìwàásù: Luuku 15:11-32  By Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

Àkọ́lé Ìwàásù: ‘Ògbólógbòó Baba Àgbà ti Àgbáyé’ (Apá Ikejila) tàbí ‘’Apá ikejidinlogun: – ‘Ní bo ní àgbárá ìwòsàn Ọlọ́run wà lákòókò àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà tó gbayé kan, báyìí? Kókó Ìwàásù: Luuku 15:11-32  By Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

 

AUGUST, 2020

Àkọ́lé Ìwàásù: ‘Ògbólógbòó Baba Àgbà ti Àgbáyé’ (Apá Ikankanla) tàbí ‘’Apá iketadinlogun: – ‘Ní bo ní àgbárá ìwòsàn Ọlọ́run wà lákòókò àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà tó gbayé kan, báyìí? Kókó Ìwàásù: Luuku 15:11-32  By Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

 

Àkọ́lé Ìwàásù: ‘Ògbólógbòó Baba Àgbà ti Àgbáyé’ (Apá Ikewa) tàbí ‘’Apá ikerindinlogun: – ‘Ní bo ní àgbárá ìwòsàn Ọlọ́run wà lákòókò àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà tó gbayé kan, báyìí? Kókó Ìwàásù: Luuku 15:11-32  By Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

 

Àkọ́lé Ìwàásù: ‘Ògbólógbòó Baba Àgbà ti Àgbáyé’ (Apá Ikesan) tàbí ‘’Apá ikarundinlogun: – ‘Ní bo ní àgbárá ìwòsàn Ọlọ́run wà lákòókò àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà tó gbayé kan, báyìí? Kókó Ìwàásù: Luuku 15:11-32  By Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

Àkọ́lé Ìwàásù: ‘Ògbólógbòó Baba Àgbà ti Àgbáyé’ (Apá Ikejo) tàbí ‘’Apá ikerinla: – ‘Ní bo ní àgbárá ìwòsàn Ọlọ́run wà lákòókò àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà tó gbayé kan, báyìí? Kókó Ìwàásù: Luuku 15:11-32  By Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

Àkọ́lé Ìwàásù: ‘Ògbólógbòó Baba Àgbà ti Àgbáyé’ (Apá keje) tàbí ‘’Apá Iketala: – ‘Ní bo ní àgbárá ìwòsàn Ọlọ́run wà lákòókò àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà tó gbayé kan, báyìí? Kókó Ìwàásù: Luuku 15:11-32  By Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

JULY 2020

Àkọ́lé Ìwàásù: ‘Ògbólógbòó Baba Àgbà ti Àgbáyé’ (Apá Kafa) ati‘’Apá Ikejila: – ‘Ní bo ní àgbárá ìwòsàn Ọlọ́run wà lákòókò àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà tó gbayé kan, báyìí? Kókó Ìwàásù: Luuku 15:11-32  By Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

Àkọ́lé Ìwàásù: ‘Ògbólógbòó Baba Àgbà ti Àgbáyé’ (Apá Karun) ati‘’Apá Kokanla: – ‘Ní bo ní àgbárá ìwòsàn Ọlọ́run wà lákòókò àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà tó gbayé kan, báyìí? Kókó Ìwàásù: Kol. 3:20-21  By Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

Àkọ́lé Ìwàásù: ‘Ògbólógbòó Baba Àgbà ti Àgbáyé’ (Apá kerin) ati‘’Apá Kẹwa: – ‘Ní bo ní àgbárá ìwòsàn Ọlọ́run wà lákòókò àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà tó gbayé kan, báyìí? Kókó Ìwàásù: Kol. 3:20-21  By Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

Àkọ́lé Ìwàásù: ‘Ògbólógbòó Baba Àgbà ti Àgbáyé’ (Apá keta) tàbí ‘’Apá Kẹsan: – ‘Ní bo ní àgbárá ìwòsàn Ọlọ́run wà lákòókò àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà tó gbayé kan, báyìí? Kókó Ìwàásù: Luku 18:34-43  By Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

 

JUNE 2020

Àkọ́lé Ìwàásù: ‘Ògbólógbòó Baba Àgbà ti Àgbáyé’ (Apá kejì) tàbí ‘’Apá Kẹjọ: – ‘Ní bo ní àgbárá ìwòsàn Ọlọ́run wà lákòókò àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà tó gbayé kan, báyìí? Kókó Ìwàásù: Romu 8:15.   By Olúṣọlà Mákindipẹ̀.

DOWNLOAD

Àkọ́lé Ìwàásù: ‘Ògbólógbòó Baba Àgbà ti Àgbáyé’ (Apá kìní). Kókó Ìwàásù: Romu 8:15. By Olusola Makindipe

DOWNLOAD

AKORI IWASU – BÁLÁÁMÙ ÀTI KETEKETE RE APA KEJI. NOMBÀ 22: 22; MÁTÍÙ 3:16-17 – TÈMÍTÁYO OKÙNOREN

DOWNLOAD NOW 

AKORI IWASU – BÁLÁÁMÙ ÀTI KETEKETE RE APA KIN-IN-NI. NOMBÀ 22: 22; MÁTÍÙ 3:16-17 – TÈMÍTÁYO OKÙNOREN

DOWNLOAD NOW 

MAY 2020

AKORI: ’APÁ KEJE: – ‘L’ OJO PENTÍKOSTÌ, NÍ BO NÍ ÀGBÁRÁ ÌWÒSÀN ỌLORUN WÀ LÁKÒÓKÒ ÀJÀKÁLE ÀRÙN KÒRÓNÀ TÓ GBAYÉ KAN, BÁYÌÍ? ÌSE ÀWON ÀPOSÍTÉLÌ 1:8, 2:1-13 BY OLÚSOLÀ MÁKINDIPE.

DOWNLOAD NOW

AKORI:’GBÍGBA ÌWÒSÀN NÍPASE ÌGBÀLÀ ÀTI ÌDÀGBÀ SÓKÈ NÍNÚ ÌGBÀGBO. TEXT: ÉFÉSÙ 1: 15, 17-18 & MÁÀKÙ 16:15. – TEMÍTÁYọ̀ ỌKÙNOOREN

DOWNLOAD NOW

AKORI;  APÁ KEFÀ: – ‘L’OJO ÌGÒKÈ RE Ọ̀RUN, NÍ BO NÍ ÀGBÁRÁ ÌWÒSÀN ỌLORUN WÀ LÁKÒÓKÒ ÀJÀKÁLE ÀRÙN KÒRÓNÀ TÓ GBAYÉ KAN, BÁYÌÍ? ÌSE ÀWON ÀPOSÍTÉLÌ 1: 9-11. BY  Olusola Makindipe

DOWNLOAD NOW

AKORI: ‘NI BO NI AGBARA IWOSAN OLORUN WA LA KO KO AJAKALE ARUN CORONA TO GBAYE KAN, BAYI (APA KARUN)’ by Olusola Makindipe

DOWNLOAD NOW

AKORI: ‘NI BO NI AGBARA IWOSAN OLORUN WA LA KO KO AJAKALE ARUN CORONA TO GBAYE KAN, BAYI (APA KERIN) By BY Olusola Makindipe

DOWNLOAD NOW

AKORI: ‘NI BO NI AGBARA IWOSAN OLORUN WA LA KO KO AJAKALE ARUN CORONA TO GBAYE KAN, BAYI (APA KETA)’ TEXT: JOHANU 10: 9-10 by Olusola Makindipe

DOWNLOAD NOW

APRIL 2020

AKORI: APAKEJI: ‘NI BO NI AGBARA IWOSAN OLORUN WA LA KO KO AJAKALE ARUN CORONA TO GBAYEKAN, BAYI?  TEXT: ROMU 8: 34  By Olusola Makindipe
 

DOWNLOAD NOW

AKORI: APAKINI: ‘NI BO NI AGBARA IWOSAN OLORUN WA LA KOKO AJAKALE ARUN CORONA TO GBAYEKAN, BAYI?  TEXT: DANIELI 6: 1-5 by Olusola Makindipe
DOWNLOAD NOW
AKORI: ‘TA LO KOKORI JESU, LOWURO OJO AJINDE? OKUNRIN NI TABI OBINRIN, JUU TABI HELENI?’TEXT: MATIU 27:62-66 BY Very Rev Olusola Makindipe
AKORI: LA KOKO ISINMI YI, SE MO SETAN KI JESU KRISTI GUN ESIN WO INU AIYE MI?  TEXT: ORIN DAFIDI 118:19-29 by  Olusola Makindipe

DOWNLOAD NOW

PASSION WEEK

IWAASU FUN OJO AJE MIMO LATI ORIN DAFIDI 36: 5-11 BY  OLUSOLA MAKINDIPE

DOWNLOAD NOW

IWAASU FUN OJO ISEGUN MIMO LATI 1 KORINTI 1: 18-31 BY  OLUSOLA MAKINDIPE

DOWNLOAD NOW

IWAASU FUN OJO’RU MIMO LATI JOHANU 13: 21-30 BY OLUSOLA MAKINDIPE

DOWNLOAD NOW

IWAASU FUN  OJO’BO MIMO LATI LUKU 22: 7-20 BY  OLUSOLA MAKINDIPE

DOWNLOAD NOW

IWAASU FUN OJO ETI MIMO: ‘SE IWO BA WON PEJO NI BI AGBARI KALFARI’ TEXTS: LUKU 23: 34, MATIU. 27: 46 & JOHANU 19: 30 BY OLUSOLA MAKINDIPE

DOWNLOAD NOW